Hello everyone 👋
My name is [MIZE], a proud student of Tech in Yoruba – Cohort 1 (2026).
I’m excited to be part of this cohort because I’m here to learn, grow, and gain wisdom that will help me build real skills in tech.

A big thank you to our instructor, Mr. Theophilus Adegbohungbe, for the teaching, guidance, and effort you’re putting into this journey. I truly appreciate it and I’m looking forward to learning more. 🙏✨

Ẹ káàbọ̀ gbogbo yín 👋
Orúkọ mi ni [MIZE], mo sì jẹ́ akẹ́kọ̀ọ́ Tech in Yoruba – Cohort 1, ọdún 2026.
Mo dùn gan-an láti jẹ́ apá kan nínú ẹgbẹ́ yìí, nítorí pé mo wà níbí láti kó ọgbọ́n, kó ìmọ̀, kí n sì túbọ̀ dá ara mi lórí nínú ẹ̀kọ́ imọ̀ ẹ̀rọ (tech).

Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ olùkọ́ wa, MR Theophilus Adegbohungbe, fún ìkọ́ni, ìtọ́sọ́nà àti àkúnya tí ẹ ń fi kọ́ wa. Ọlọ́run á bù kún yín, mo sì mọrírì gbogbo ìsapá yín gan-an 🙏

Inú mi dùn láti wà pẹ̀lú yín — ẹ jẹ́ ká kọ́, ká sì dàgbà pọ̀ 💡🚀